Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 174 - النِّسَاء - Page - Juz 6
﴿يَٰٓأَيُّهَا ٱلنَّاسُ قَدۡ جَآءَكُم بُرۡهَٰنٞ مِّن رَّبِّكُمۡ وَأَنزَلۡنَآ إِلَيۡكُمۡ نُورٗا مُّبِينٗا ﴾
[النِّسَاء: 174]
﴿ياأيها الناس قد جاءكم برهان من ربكم وأنـزلنا إليكم نورا مبينا﴾ [النِّسَاء: 174]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀yin ènìyàn, dájúdájú ẹ̀rí ọ̀rọ̀ ti dé ba yín láti ọ̀dọ̀ Olúwa yín. A sì tún sọ ìmọ́lẹ̀ t’ó yanjú kalẹ̀ fun yín |