Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 45 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿وَٱللَّهُ أَعۡلَمُ بِأَعۡدَآئِكُمۡۚ وَكَفَىٰ بِٱللَّهِ وَلِيّٗا وَكَفَىٰ بِٱللَّهِ نَصِيرٗا ﴾
[النِّسَاء: 45]
﴿والله أعلم بأعدائكم وكفى بالله وليا وكفى بالله نصيرا﴾ [النِّسَاء: 45]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu sì nímọ̀ jùlọ nípa àwọn ọ̀tá yín. Allāhu tó ní Aláàbò. Allāhu sì tó ní Alárànṣe |