Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 41 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿أَمۡ عِندَهُمُ ٱلۡغَيۡبُ فَهُمۡ يَكۡتُبُونَ ﴾
[الطُّور: 41]
﴿أم عندهم الغيب فهم يكتبون﴾ [الطُّور: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí ìmọ̀ ìkọ̀kọ̀ wà lọ́dọ̀ wọn, tí wọ́n sì ń kọ ọ́ sílẹ̀ |