Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 42 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿أَمۡ يُرِيدُونَ كَيۡدٗاۖ فَٱلَّذِينَ كَفَرُواْ هُمُ ٱلۡمَكِيدُونَ ﴾
[الطُّور: 42]
﴿أم يريدون كيدا فالذين كفروا هم المكيدون﴾ [الطُّور: 42]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí wọ́n ń gbèrò ète kan ni? Nígbà náà, àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́, àwọn l’ó máa f’orí kó ète |