Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 40 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿أَمۡ تَسۡـَٔلُهُمۡ أَجۡرٗا فَهُم مِّن مَّغۡرَمٖ مُّثۡقَلُونَ ﴾
[الطُّور: 40]
﴿أم تسألهم أجرا فهم من مغرم مثقلون﴾ [الطُّور: 40]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí ò ń bèèrè owó-ọ̀yà kan lọ́dọ̀ wọn, ni gbèsè fi wọ̀ wọ́n lọ́rùn |