Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 58 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿أَفَرَءَيۡتُم مَّا تُمۡنُونَ ﴾
[الوَاقِعة: 58]
﴿أفرأيتم ما تمنون﴾ [الوَاقِعة: 58]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ sọ fún Mi nípa àtọ̀ tí ẹ̀ ń dà jáde (sínú àpòlùkẹ́) |