Quran with Yoruba translation - Surah Al-hadid ayat 2 - الحدِيد - Page - Juz 27
﴿لَهُۥ مُلۡكُ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۖ يُحۡيِۦ وَيُمِيتُۖ وَهُوَ عَلَىٰ كُلِّ شَيۡءٖ قَدِيرٌ ﴾
[الحدِيد: 2]
﴿له ملك السموات والأرض يحيي ويميت وهو على كل شيء قدير﴾ [الحدِيد: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni TiRẹ̀ ni ìjọba àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀. Ó ń sọ ẹ̀dá di alààyè. Ó sì ń sọ ẹ̀dá di òkú. Òun ni Alágbára lórí gbogbo n̄ǹkan |