Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 48 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿وَإِنَّهُۥ لَتَذۡكِرَةٞ لِّلۡمُتَّقِينَ ﴾
[الحَاقة: 48]
﴿وإنه لتذكرة للمتقين﴾ [الحَاقة: 48]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú (al-Ƙur’ān) ni ìrántí fún àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu) |