Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 196 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿إِنَّ وَلِـِّۧيَ ٱللَّهُ ٱلَّذِي نَزَّلَ ٱلۡكِتَٰبَۖ وَهُوَ يَتَوَلَّى ٱلصَّٰلِحِينَ ﴾
[الأعرَاف: 196]
﴿إن وليي الله الذي نـزل الكتاب وهو يتولى الصالحين﴾ [الأعرَاف: 196]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Alátìlẹ́yìn mi ni Allāhu, Ẹni tí Ó sọ Tírà náà kalẹ̀. Àti pé Òun l’Ó ń ṣàtìlẹ́yìn fún àwọn ẹni rere |