Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qiyamah ayat 17 - القِيَامة - Page - Juz 29
﴿إِنَّ عَلَيۡنَا جَمۡعَهُۥ وَقُرۡءَانَهُۥ ﴾
[القِيَامة: 17]
﴿إن علينا جمعه وقرآنه﴾ [القِيَامة: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa l’A máa ṣe ìkójọ rẹ̀ (sínú ọkàn rẹ) àti kíké rẹ̀ |