Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mursalat ayat 36 - المُرسَلات - Page - Juz 29
﴿وَلَا يُؤۡذَنُ لَهُمۡ فَيَعۡتَذِرُونَ ﴾
[المُرسَلات: 36]
﴿ولا يؤذن لهم فيعتذرون﴾ [المُرسَلات: 36]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A ò sì níí yọ̀ǹda (ọ̀rọ̀ sísọ) fún wọn, áḿbọ̀sìbọ́sí pé wọ́n yóò mú àwáwí wá |