Quran with Yoruba translation - Surah An-Nazi‘at ayat 2 - النَّازعَات - Page - Juz 30
﴿وَٱلنَّٰشِطَٰتِ نَشۡطٗا ﴾
[النَّازعَات: 2]
﴿والناشطات نشطا﴾ [النَّازعَات: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó tún búra pẹ̀lú àwọn mọlāika t’ó ń fi ọ̀nà ẹ̀rọ̀ gba ẹ̀mí àwọn onígbàgbọ́ òdodo |