Quran with Yoruba translation - Surah An-Nazi‘at ayat 1 - النَّازعَات - Page - Juz 30
﴿وَٱلنَّٰزِعَٰتِ غَرۡقٗا ﴾
[النَّازعَات: 1]
﴿والنازعات غرقا﴾ [النَّازعَات: 1]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu búra pẹ̀lú àwọn mọlāika t’ó ń fi ọ̀nà èle gba ẹ̀mí àwọn aláìgbàgbọ́ |