Quran with Yoruba translation - Surah At-Takwir ayat 16 - التَّكوير - Page - Juz 30
﴿ٱلۡجَوَارِ ٱلۡكُنَّسِ ﴾
[التَّكوير: 16]
﴿الجوار الكنس﴾ [التَّكوير: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (ìyẹn) àwọn ìràwọ̀ t’ó ń rìn lọ rìn bọ̀, t’ó ń wọ̀ọ̀kùn sí ibùwọ̀ wọn |