Quran with Yoruba translation - Surah At-Takwir ayat 15 - التَّكوير - Page - Juz 30
﴿فَلَآ أُقۡسِمُ بِٱلۡخُنَّسِ ﴾
[التَّكوير: 15]
﴿فلا أقسم بالخنس﴾ [التَّكوير: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, Èmi (Allāhu) ń búra pẹ̀lú àwọn ìràwọ̀ t’ó ń yọ ní alẹ́, t’ó ń wọ̀ọ̀kùn ní ọ̀sán |