Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fajr ayat 26 - الفَجر - Page - Juz 30
﴿وَلَا يُوثِقُ وَثَاقَهُۥٓ أَحَدٞ ﴾
[الفَجر: 26]
﴿ولا يوثق وثاقه أحد﴾ [الفَجر: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnì kan kò sì lè de (ẹ̀dá) ní ìgbèkùn bí irú ìgbèkùn (tí) Allāhu (yóò fi dè é) |