Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fajr ayat 25 - الفَجر - Page - Juz 30
﴿فَيَوۡمَئِذٖ لَّا يُعَذِّبُ عَذَابَهُۥٓ أَحَدٞ ﴾
[الفَجر: 25]
﴿فيومئذ لا يعذب عذابه أحد﴾ [الفَجر: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ọjọ́ yẹn, ẹnì kan kò lè fi ìyà jẹ (ẹ̀dá) bí irú ìyà (tí) Allāhu (yóò fi jẹ ẹ́) |