Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shams ayat 3 - الشَّمس - Page - Juz 30
﴿وَٱلنَّهَارِ إِذَا جَلَّىٰهَا ﴾
[الشَّمس: 3]
﴿والنهار إذا جلاها﴾ [الشَّمس: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó tún búra pẹ̀lú ọ̀sán nígbà tí ó bá mú ìmọ́lẹ̀ bá òkùnkùn òru |