×

O si n be ninu won eni t’o gba a gbo ni 10:40 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Yunus ⮕ (10:40) ayat 40 in Yoruba

10:40 Surah Yunus ayat 40 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 40 - يُونس - Page - Juz 11

﴿وَمِنۡهُم مَّن يُؤۡمِنُ بِهِۦ وَمِنۡهُم مَّن لَّا يُؤۡمِنُ بِهِۦۚ وَرَبُّكَ أَعۡلَمُ بِٱلۡمُفۡسِدِينَ ﴾
[يُونس: 40]

O si n be ninu won eni t’o gba a gbo ni ododo. O tun n be ninu won eni ti ko gba a gbo. Oluwa re si ni Onimo-julo nipa awon obileje

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ومنهم من يؤمن به ومنهم من لا يؤمن به وربك أعلم بالمفسدين, باللغة اليوربا

﴿ومنهم من يؤمن به ومنهم من لا يؤمن به وربك أعلم بالمفسدين﴾ [يُونس: 40]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ó sì ń bẹ nínú wọn ẹni t’ó gbà á gbọ́ ní òdodo. Ó tún ń bẹ́ nínú wọn ẹni tí kò gbà á gbọ́. Olúwa rẹ sì ni Onímọ̀-jùlọ nípa àwọn òbìlẹ̀jẹ́
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek