Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 115 - هُود - Page - Juz 12
﴿وَٱصۡبِرۡ فَإِنَّ ٱللَّهَ لَا يُضِيعُ أَجۡرَ ٱلۡمُحۡسِنِينَ ﴾
[هُود: 115]
﴿واصبر فإن الله لا يضيع أجر المحسنين﴾ [هُود: 115]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣe sùúrù. Dájúdájú Allāhu kò níí fi ẹ̀san àwọn olùṣe-rere ráre |