Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 1 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿الٓرۚ تِلۡكَ ءَايَٰتُ ٱلۡكِتَٰبِ وَقُرۡءَانٖ مُّبِينٖ ﴾
[الحِجر: 1]
﴿الر تلك آيات الكتاب وقرآن مبين﴾ [الحِجر: 1]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni ’Alif lām rọ̄. Ìwọ̀nyí ni àwọn āyah Tírà náà àti (àwọn āyah) al-Ƙur’ān t’ó ń yanjú ọ̀rọ̀ ẹ̀dá |