Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 2 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿رُّبَمَا يَوَدُّ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ لَوۡ كَانُواْ مُسۡلِمِينَ ﴾
[الحِجر: 2]
﴿ربما يود الذين كفروا لو كانوا مسلمين﴾ [الحِجر: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó ṣeé ṣe kí àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ nífẹ̀ẹ́ sí pé àwọn ìbá sì ti jẹ́ mùsùlùmí (nílé ayé) |