Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 93 - الكَهف - Page - Juz 16
﴿حَتَّىٰٓ إِذَا بَلَغَ بَيۡنَ ٱلسَّدَّيۡنِ وَجَدَ مِن دُونِهِمَا قَوۡمٗا لَّا يَكَادُونَ يَفۡقَهُونَ قَوۡلٗا ﴾
[الكَهف: 93]
﴿حتى إذا بلغ بين السدين وجد من دونهما قوما لا يكادون يفقهون﴾ [الكَهف: 93]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni títí ó fi dé ààrin àpáta méjì. Ó sì bá àwọn ènìyàn kan níwájú rẹ̀. Wọn kò sì fẹ́ẹ̀ gbọ́ àgbọ́yé ọ̀rọ̀ kan (nínú èdè mìíràn) |