Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 13 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَحَنَانٗا مِّن لَّدُنَّا وَزَكَوٰةٗۖ وَكَانَ تَقِيّٗا ﴾
[مَريَم: 13]
﴿وحنانا من لدنا وزكاة وكان تقيا﴾ [مَريَم: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì Yahyā jẹ́) ìkẹ́ àti ẹni mímọ́ kan láti ọ̀dọ̀ Wa. Ó sì jẹ́ olùbẹ̀rù (Allāhu) |