Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 14 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَبَرَّۢا بِوَٰلِدَيۡهِ وَلَمۡ يَكُن جَبَّارًا عَصِيّٗا ﴾
[مَريَم: 14]
﴿وبرا بوالديه ولم يكن جبارا عصيا﴾ [مَريَم: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ó tún jẹ́) oníwà rere sí àwọn òbí rẹ̀ méjèèjì. Kò sì jẹ́ ajẹninípá, olùyapa |