Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 51 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَٱذۡكُرۡ فِي ٱلۡكِتَٰبِ مُوسَىٰٓۚ إِنَّهُۥ كَانَ مُخۡلَصٗا وَكَانَ رَسُولٗا نَّبِيّٗا ﴾
[مَريَم: 51]
﴿واذكر في الكتاب موسى إنه كان مخلصا وكان رسولا نبيا﴾ [مَريَم: 51]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ ìtàn (Ànábì) Mūsā tí ó wà nínú al-Ƙur’ān. Dájúdájú ó jẹ́ ẹni-ẹ̀ṣà, ó jẹ́ Òjíṣẹ́, (ó tún jẹ́) Ànábì |