Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 176 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿ذَٰلِكَ بِأَنَّ ٱللَّهَ نَزَّلَ ٱلۡكِتَٰبَ بِٱلۡحَقِّۗ وَإِنَّ ٱلَّذِينَ ٱخۡتَلَفُواْ فِي ٱلۡكِتَٰبِ لَفِي شِقَاقِۭ بَعِيدٖ ﴾
[البَقَرَة: 176]
﴿ذلك بأن الله نـزل الكتاب بالحق وإن الذين اختلفوا في الكتاب لفي﴾ [البَقَرَة: 176]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn rí bẹ́ẹ̀ nítorí pé dájúdájú Allāhu sọ Tírà (al-Ƙur’ān) kalẹ̀ pẹ̀lú òdodo. Dájúdájú àwọn t’ó sì yapa Tírà náà ti wà nínú ìyapà t’ó jìnnà (sí òdodo) |