Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 13 - طه - Page - Juz 16
﴿وَأَنَا ٱخۡتَرۡتُكَ فَٱسۡتَمِعۡ لِمَا يُوحَىٰٓ ﴾
[طه: 13]
﴿وأنا اخترتك فاستمع لما يوحى﴾ [طه: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé Èmi ṣà ọ́ lẹ́ṣà. Nítorí náà, fi etí sí ohun tí A máa fi ránṣẹ́ sí ọ nínú ìmísí |