Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 12 - طه - Page - Juz 16
﴿إِنِّيٓ أَنَا۠ رَبُّكَ فَٱخۡلَعۡ نَعۡلَيۡكَ إِنَّكَ بِٱلۡوَادِ ٱلۡمُقَدَّسِ طُوٗى ﴾
[طه: 12]
﴿إني أنا ربك فاخلع نعليك إنك بالواد المقدس طوى﴾ [طه: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Èmi ni Olúwa rẹ. Nítorí náà, bọ́ bàtà rẹ méjèèjì sílẹ̀. Dájúdájú ìwọ wà ní àfonífojì mímọ́, Tuwā |