Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 68 - طه - Page - Juz 16
﴿قُلۡنَا لَا تَخَفۡ إِنَّكَ أَنتَ ٱلۡأَعۡلَىٰ ﴾
[طه: 68]
﴿قلنا لا تخف إنك أنت الأعلى﴾ [طه: 68]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sọ pé: "Má ṣe páyà. Dájúdájú ìwọ, ìwọ lo máa lékè |