Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 95 - طه - Page - Juz 16
﴿قَالَ فَمَا خَطۡبُكَ يَٰسَٰمِرِيُّ ﴾
[طه: 95]
﴿قال فما خطبك ياسامري﴾ [طه: 95]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì Mūsā) sọ pé: “Kí ni ọ̀rọ̀ tìrẹ ti jẹ́, Sāmiriyy?” |