Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 107 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَمَآ أَرۡسَلۡنَٰكَ إِلَّا رَحۡمَةٗ لِّلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 107]
﴿وما أرسلناك إلا رحمة للعالمين﴾ [الأنبيَاء: 107]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A kò sì fi iṣẹ́ ìmísí rán ọ bí kò ṣe pé kí o lè jẹ́ ìkẹ́ fún gbogbo ẹ̀dá |