Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 106 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿إِنَّ فِي هَٰذَا لَبَلَٰغٗا لِّقَوۡمٍ عَٰبِدِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 106]
﴿إن في هذا لبلاغا لقوم عابدين﴾ [الأنبيَاء: 106]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú ohun t’ó tó mú ni gúnlẹ̀ sínú Ọgbà Ìdẹ̀ra ti wà nínú (al-Ƙur’ān) yìí fún ìjọ olùjọ́sìn (fún Mi) |