Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 118 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿وَقُل رَّبِّ ٱغۡفِرۡ وَٱرۡحَمۡ وَأَنتَ خَيۡرُ ٱلرَّٰحِمِينَ ﴾
[المؤمنُون: 118]
﴿وقل رب اغفر وارحم وأنت خير الراحمين﴾ [المؤمنُون: 118]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Olúwa mi, ṣàforíjìn, kí O sì kẹ́ (mi). Ìwọ sì l’óore jùlọ nínú àwọn aláàánú.” |