Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 79 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿وَهُوَ ٱلَّذِي ذَرَأَكُمۡ فِي ٱلۡأَرۡضِ وَإِلَيۡهِ تُحۡشَرُونَ ﴾
[المؤمنُون: 79]
﴿وهو الذي ذرأكم في الأرض وإليه تحشرون﴾ [المؤمنُون: 79]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òun ni Ẹni tí Ó da yín sórí ilẹ̀, ọ̀dọ̀ Rẹ̀ sì ni wọ́n yóò ko yín jọ sí |