Quran with Yoruba translation - Surah An-Nur ayat 7 - النور - Page - Juz 18
﴿وَٱلۡخَٰمِسَةُ أَنَّ لَعۡنَتَ ٱللَّهِ عَلَيۡهِ إِن كَانَ مِنَ ٱلۡكَٰذِبِينَ ﴾
[النور: 7]
﴿والخامسة أن لعنة الله عليه إن كان من الكاذبين﴾ [النور: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀ẹ̀ karùn-ún sì ni pé kí ibi dandan Allāhu máa bá òun, tí òun bá wà nínú àwọn òpùrọ́ |