Quran with Yoruba translation - Surah An-Nur ayat 9 - النور - Page - Juz 18
﴿وَٱلۡخَٰمِسَةَ أَنَّ غَضَبَ ٱللَّهِ عَلَيۡهَآ إِن كَانَ مِنَ ٱلصَّٰدِقِينَ ﴾
[النور: 9]
﴿والخامسة أن غضب الله عليها إن كان من الصادقين﴾ [النور: 9]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀ẹ̀ karùn-ún sì ni pé kí ìbínú Allāhu máa bá òun, tí ọkọ òun bá wà nínú àwọn olódodo |