Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 165 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿أَتَأۡتُونَ ٱلذُّكۡرَانَ مِنَ ٱلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الشعراء: 165]
﴿أتأتون الذكران من العالمين﴾ [الشعراء: 165]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé àwọn ọkùnrin nínú ẹ̀dá ni ẹ̀yin ọkùnrin yóò lọ máa bá (fún adùn ìbálòpọ̀) |