Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 36 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿قَالُوٓاْ أَرۡجِهۡ وَأَخَاهُ وَٱبۡعَثۡ فِي ٱلۡمَدَآئِنِ حَٰشِرِينَ ﴾
[الشعراء: 36]
﴿قالوا أرجه وأخاه وابعث في المدائن حاشرين﴾ [الشعراء: 36]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: "Dá òun àti arákùnrin rẹ̀ dúró ná, kí o sì rán àwọn akónijọ sí àwọn ìlú |