Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 79 - النَّمل - Page - Juz 20
﴿فَتَوَكَّلۡ عَلَى ٱللَّهِۖ إِنَّكَ عَلَى ٱلۡحَقِّ ٱلۡمُبِينِ ﴾
[النَّمل: 79]
﴿فتوكل على الله إنك على الحق المبين﴾ [النَّمل: 79]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, gbáralé Allāhu. Dájúdájú ìwọ wà lórí òdodo pọ́nńbélé |