Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 11 - العَنكبُوت - Page - Juz 20
﴿وَلَيَعۡلَمَنَّ ٱللَّهُ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَلَيَعۡلَمَنَّ ٱلۡمُنَٰفِقِينَ ﴾
[العَنكبُوت: 11]
﴿وليعلمن الله الذين آمنوا وليعلمن المنافقين﴾ [العَنكبُوت: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Allāhu máa ṣàfi hàn àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo. Ó sì máa ṣàfi hàn àwọn ṣọ̀be-ṣèlu mùsùlùmí |