×

Ki awon t’o sai gbagbo ma se lero pe bi A se 3:178 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah al-‘Imran ⮕ (3:178) ayat 178 in Yoruba

3:178 Surah al-‘Imran ayat 178 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 178 - آل عِمران - Page - Juz 4

﴿وَلَا يَحۡسَبَنَّ ٱلَّذِينَ كَفَرُوٓاْ أَنَّمَا نُمۡلِي لَهُمۡ خَيۡرٞ لِّأَنفُسِهِمۡۚ إِنَّمَا نُمۡلِي لَهُمۡ لِيَزۡدَادُوٓاْ إِثۡمٗاۖ وَلَهُمۡ عَذَابٞ مُّهِينٞ ﴾
[آل عِمران: 178]

Ki awon t’o sai gbagbo ma se lero pe bi A se n lora fun won je oore fun won. A kan n lora fun won nitori ki won le lekun ninu ese ni. Iya ti i yepere eda si wa fun won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ولا يحسبن الذين كفروا أنما نملي لهم خير لأنفسهم إنما نملي لهم, باللغة اليوربا

﴿ولا يحسبن الذين كفروا أنما نملي لهم خير لأنفسهم إنما نملي لهم﴾ [آل عِمران: 178]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Kí àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ má ṣe lérò pé bí A ṣe ń lọ́ra fún wọn jẹ́ oore fún wọn. A kàn ń lọ́ra fún wọn nítorí kí wọ́n lè lékún nínú ẹ̀ṣẹ̀ ni. Ìyà tí í yẹpẹrẹ ẹ̀dá sì wà fún wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek