Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 58 - آل عِمران - Page - Juz 3
﴿ذَٰلِكَ نَتۡلُوهُ عَلَيۡكَ مِنَ ٱلۡأٓيَٰتِ وَٱلذِّكۡرِ ٱلۡحَكِيمِ ﴾
[آل عِمران: 58]
﴿ذلك نتلوه عليك من الآيات والذكر الحكيم﴾ [آل عِمران: 58]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn ni À ń ké fún ọ nínú àwọn āyah àti ìrántí tí ó kún fún ọgbọ́n ìjìnlẹ̀ (ìyẹn, al-Ƙur’ān) |