Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 72 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿وَذَلَّلۡنَٰهَا لَهُمۡ فَمِنۡهَا رَكُوبُهُمۡ وَمِنۡهَا يَأۡكُلُونَ ﴾
[يسٓ: 72]
﴿وذللناها لهم فمنها ركوبهم ومنها يأكلون﴾ [يسٓ: 72]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A tẹ̀ wọ́n lórí ba fún wọn; wọ́n ń gùn nínú wọn, wọ́n sì ń jẹ nínú wọn |