Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 134 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿إِذۡ نَجَّيۡنَٰهُ وَأَهۡلَهُۥٓ أَجۡمَعِينَ ﴾
[الصَّافَات: 134]
﴿إذ نجيناه وأهله أجمعين﴾ [الصَّافَات: 134]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ẹ rántí) nígbà tí A gba òun àti gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀ là |