Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 50 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿فَأَقۡبَلَ بَعۡضُهُمۡ عَلَىٰ بَعۡضٖ يَتَسَآءَلُونَ ﴾
[الصَّافَات: 50]
﴿فأقبل بعضهم على بعض يتساءلون﴾ [الصَّافَات: 50]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Apá kan wọn yóò dojú kọ apá kan, tí wọn yóò máa bira wọn léèrè ìbéèrè |