Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 21 - صٓ - Page - Juz 23
﴿۞ وَهَلۡ أَتَىٰكَ نَبَؤُاْ ٱلۡخَصۡمِ إِذۡ تَسَوَّرُواْ ٱلۡمِحۡرَابَ ﴾
[صٓ: 21]
﴿وهل أتاك نبأ الخصم إذ تسوروا المحراب﴾ [صٓ: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ǹjẹ́ ìró àwọn oníjà ti dé ọ̀dọ̀ rẹ; nígbà tí wọ́n pọ́n ògiri ilé ìjọ́sìn |