Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 138 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿بَشِّرِ ٱلۡمُنَٰفِقِينَ بِأَنَّ لَهُمۡ عَذَابًا أَلِيمًا ﴾
[النِّسَاء: 138]
﴿بشر المنافقين بأن لهم عذابا أليما﴾ [النِّسَاء: 138]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Fún àwọn ṣọ̀bẹ-ṣèlu mùsùlùmí ní ìró pé dájúdájú ìyà ẹlẹ́ta eléro ń bẹ fún wọn |