Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 145 - النِّسَاء - Page - Juz 5
﴿إِنَّ ٱلۡمُنَٰفِقِينَ فِي ٱلدَّرۡكِ ٱلۡأَسۡفَلِ مِنَ ٱلنَّارِ وَلَن تَجِدَ لَهُمۡ نَصِيرًا ﴾
[النِّسَاء: 145]
﴿إن المنافقين في الدرك الأسفل من النار ولن تجد لهم نصيرا﴾ [النِّسَاء: 145]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn ṣọ̀be-ṣèlu mùsùlùmí yóò wà nínú àjà ìsàlẹ̀ pátápátá nínú Iná. O ò sì níí rí alárànṣe kan fún wọn |