×

Awon t’o n sahun, (awon) t’o n pa eniyan lase ahun sise 4:37 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Nisa’ ⮕ (4:37) ayat 37 in Yoruba

4:37 Surah An-Nisa’ ayat 37 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Nisa’ ayat 37 - النِّسَاء - Page - Juz 5

﴿ٱلَّذِينَ يَبۡخَلُونَ وَيَأۡمُرُونَ ٱلنَّاسَ بِٱلۡبُخۡلِ وَيَكۡتُمُونَ مَآ ءَاتَىٰهُمُ ٱللَّهُ مِن فَضۡلِهِۦۗ وَأَعۡتَدۡنَا لِلۡكَٰفِرِينَ عَذَابٗا مُّهِينٗا ﴾
[النِّسَاء: 37]

Awon t’o n sahun, (awon) t’o n pa eniyan lase ahun sise ati (awon) t’o n fi ohun ti Allahu fun won ninu oore ajulo Re pamo; A ti pese iya ti i yepere eda sile de awon alaigbagbo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: الذين يبخلون ويأمرون الناس بالبخل ويكتمون ما آتاهم الله من فضله وأعتدنا, باللغة اليوربا

﴿الذين يبخلون ويأمرون الناس بالبخل ويكتمون ما آتاهم الله من فضله وأعتدنا﴾ [النِّسَاء: 37]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn t’ó ń ṣahun, (àwọn) t’ó ń pa ènìyàn láṣẹ ahun ṣíṣe àti (àwọn) t’ó ń fi ohun tí Allāhu fún wọn nínú oore àjùlọ Rẹ̀ pamọ́; A ti pèsè ìyà tí í yẹpẹrẹ ẹ̀dá sílẹ̀ de àwọn aláìgbàgbọ́
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek